Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwọn ìtumọ̀ Bíbélì kan tú ọ̀rọ̀ náà “akúrẹtẹ̀” sí “aláìní,” àwọn míì sì tú u sí “alágbe” tàbí ohun tí kò wúlò.