a Mẹ́ríbà yìí yàtọ̀ sí Mẹ́ríbà tó wà nítòsí Réfídímù. Àkọ́kọ́ wà nítòsí Másà, ìkejì yìí sì wà nítòsí Kádéṣì. Wọ́n sọ àgbègbè méjèèjì yìí ní Mẹ́ríbà nítorí aáwọ̀ tó ṣẹlẹ̀ níbẹ̀.—Wo àwòrán ilẹ̀ tó wà ní Apá 7 nínú ìwé Àfikún Ìsọfúnni Láti Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.