Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Nígbà tí Ọ̀jọ̀gbọ́n John A. Beck ń sọ nípa ìtàn yìí, ó ní: “Ìtàn àtẹnudẹ́nu àwọn Júù kan sọ pé, àwọn ọlọ̀tẹ̀ yẹn ráhùn sí Mósè pé: ‘Mósè mọ̀ pé àpáta yìí ò fi bẹ́ẹ̀ lágbára! Tó bá jẹ́ pé lóòótọ́ ló fẹ́ ṣe iṣẹ́ ìyanu, kó mú omi jáde látinú àpáta míì.’ ” Àmọ́ ìtàn àtẹnudẹ́nu lásán lèyí.