Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Lẹ́yìn tí Jósẹ́fù kúrò lẹ́wọ̀n, ó gbà pé Jèhófà ló fún òun ní ọmọkùnrin kan kó lè fi tu òun nínú. Ó sọ ọmọ náà ní Mánásè, ó sì sọ pé: “Ọlọ́run ti mú kí n gbàgbé gbogbo ìdààmú mi.”—Jẹ́n. 41:51.