Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Òótọ́ kan ni pé èrò àwọn míì ṣì máa ń nípa lórí irú àwọn ẹni bẹ́ẹ̀. Bí àpẹẹrẹ, èrò àwọn míì máa ń nípa lórí wa tó bá kan ohun tá a gbà gbọ́ tàbí lórí àwọn ọ̀rọ̀ míì bí aṣọ tá a máa wọ̀. Àmọ́, àwa fúnra wa la máa pinnu ẹni tá a fẹ́ kó nípa lórí wa.