Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Tó bá yá, a máa sọ̀rọ̀ nípa ìwà rere nínú àpilẹ̀kọ alápá mẹ́sàn-án tá a ti ń jíròrò èso ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run.