Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀLÀYÉ Ọ̀RỌ̀: Tẹ́nì kan bá ṣèlérí fún wa, ṣe lonítọ̀hún ń fi wá lọ́kàn balẹ̀ pé òun máa ṣe ohun tí òun sọ láìyẹhùn. Àwọn ìlérí tí Jèhófà ṣe fún wa mú kí ọkàn wa balẹ̀ láìka àwọn ìṣòro tá a ní sí.