Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀWÒRÁN: Àwòrán àwọn tó ń ṣe Ìrántí Ikú Kristi ní ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní; àwọn tó ṣe é ní nǹkan bí ọdún 1880; àwọn tó ṣe é nínú àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ ìjọba Násì àtàwọn tó ń ṣe é lóde òní ní Gbọ̀ngàn Ìjọba kan tó wà nílẹ̀ olóoru kan ní South America.