Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé e ÀWÒRÁN: Arákùnrin kan kọ̀ láti ra tẹlifíṣọ̀n ńlá tó wọ́n gan-an torí pé kò nílò rẹ̀, kò sì lówó rẹ̀.