Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Orúkọ táwọn ará Bábílónì fún àwọn ọ̀dọ́ Hébérù mẹ́ta yẹn ni Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò.—Dán. 1:7.