Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tó bá di pé kéèyàn fi ìmoore hàn, kí la rí kọ́ lára Jèhófà, Jésù àti adẹ́tẹ̀ kan tó jẹ́ ará Samáríà? A máa jíròrò àwọn àpẹẹrẹ yìí àtàwọn míì. A tún máa sọ ìdí tó fi yẹ ká máa dúpẹ́ oore, àá sì sọ àwọn ọ̀nà pàtó tá a lè gbà ṣe bẹ́ẹ̀.