Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tá a bá ń gba tàwọn míì rò, a máa láyọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù, iṣẹ́ wa á sì sèso rere. Kí nìdí tó fi rí bẹ́ẹ̀? Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa kẹ́kọ̀ọ́ látinú àpẹẹrẹ Jésù, a sì tún máa jíròrò ohun mẹ́rin tá a lè ṣe táá fi hàn pé à ń gba tàwọn èèyàn rò lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù.