Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀLÀYÉ Ọ̀RỌ̀: Bí wọ́n ṣe lo àánú nínú ẹsẹ Bíbélì yìí túmọ̀ sí pé kéèyàn ní ìmọ̀lára fún ẹnì kan tó ń jìyà tàbí tí wọ́n ti fojú ẹ̀ rí màbo. Irú ìmọ̀lára bẹ́ẹ̀ máa ń jẹ́ kéèyàn ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe láti ran ẹni náà lọ́wọ́.