Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a O lè máa ronú pé ṣé kó o ṣèrìbọmi tàbí kó o má ṣèrìbọmi? Èyí ni ìpinnu tó ṣe pàtàkì jù lọ tó o máa ṣe láyé rẹ. Kí ló mú kọ́rọ̀ yìí ṣe pàtàkì tó bẹ́ẹ̀? A máa dáhùn ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ yìí. A tún máa jíròrò àwọn nǹkan tó lè mú kẹ́nì kan máa fà sẹ́yìn láti ṣèrìbọmi, àá sì rí àwọn nǹkan táá mú kó borí àwọn ìṣòro náà.