Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé i ÀWÒRÁN: Inúnibíni: ọ̀dọ́kùnrin kan fìgboyà ṣàlàyé ohun tó gbà gbọ́ fún ìyá rẹ̀ tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí.