Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jésù gbéṣẹ́ fún wa pé ká máa wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run, ká sì máa sọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bá a ṣe lè ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa láṣeyanjú bí nǹkan ò tiẹ̀ fara rọ fún wa. Àá tún sọ àwọn nǹkan táá jẹ́ ká túbọ̀ já fáfá lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù kí ayọ̀ wa sì túbọ̀ pọ̀ sí i.