Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Gbogbo wa la ní àwọn ìṣòro tó ń kó wa lọ́kàn sókè. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò ohun mẹ́ta tí Jésù ṣe táwa náà lè fara wé. Èyí á jẹ́ kọ́kàn wa balẹ̀ kódà tá a bá ń kojú ìṣòro tó le gan-an.