Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀pọ̀ àwọn tí wọ́n ti bá ṣèṣekúṣe nígbà tí wọ́n wà lọ́mọdé ṣì máa ń ní ọgbẹ́ ọkàn kódà lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọdún. Àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká mọ ìdí tọ́rọ̀ fi rí bẹ́ẹ̀. A tún máa rí àwọn tó lè pèsè ìtùnú fún àwọn tírú ẹ̀ ṣẹlẹ̀ sí. Lẹ́yìn náà, a máa jíròrò àwọn ọ̀nà tá a lè gbà tù wọ́n nínú.