Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀pọ̀ nǹkan ni Jèhófà ń pèsè fún wa. Mélòó la fẹ́ kà lára àwọn ìwé, àwọn fídíò àtàwọn nǹkan míì tá à ń gbádùn. Àpilẹ̀kọ yìí á jẹ́ kó o mọ bó o ṣe lè kẹ́kọ̀ọ́ àti bó o ṣe lè jàǹfààní ní kíkún látinú ìdákẹ́kọ̀ọ́ rẹ.