Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bá a ṣe lè dáàbò bo àwọn ọmọdé kí wọ́n má bàa kó sọ́wọ́ àwọn tó ń bọ́mọdé ṣèṣekúṣe. A máa ṣàlàyé ohun táwọn alàgbà máa ṣe tírú ẹ̀ bá ṣẹlẹ̀ nínú ìjọ àti bí àwọn òbí ṣe lè dáàbò bo àwọn ọmọ wọn.