Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
e Kò pọn dandan kọ́mọ náà sọ tẹnu ẹ̀ lójú ẹni tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó bá a ṣèṣekúṣe. Ó lè jẹ́ òbí tàbí ẹnì kan tọ́mọ náà fọkàn tán ló máa gbẹnu sọ fún ọmọ náà níṣojú ẹni tí wọ́n fẹ̀sùn kàn. Ìyẹn ò ní jẹ́ kí wọ́n dá kún ọgbẹ́ ọkàn tọ́mọ náà ní.