Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Sátánì gbọ́n gan-an, ó sì mọ bí wọ́n ṣe ń tan àwọn èèyàn jẹ. Ó ti mú kí ọ̀pọ̀ máa ronú pé àwọn lómìnira láìmọ̀ pé inú akóló rẹ̀ ni wọ́n wà. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa ṣàlàyé díẹ̀ nínú àwọn ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ tí Sátánì máa ń lò láti tan àwọn èèyàn jẹ.