Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d ÀWÒRÁN: Arábìnrin kan wà ní yunifásítì. Olùkọ́ wọn ń kọ́ wọn pé ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ló lè yanjú ìṣòro aráyé, arábìnrin yìí àtàwọn yòókù sì fara mọ́ èrò rẹ̀. Nígbà tó lọ sípàdé, ohun tí wọ́n ń sọ níbẹ̀ ò bá a lára mu torí náà kò fọkàn sí i.