Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Téèyàn bá ní ìdààmú ọkàn tí kò sì lọ bọ̀rọ̀, ó lè jẹ́ kéèyàn ṣàárẹ̀ kó sì rẹ̀wẹ̀sì. Báwo ni Jèhófà ṣe lè ràn wá lọ́wọ́? A máa rí bí Jèhófà ṣe ran Èlíjà lọ́wọ́ láti fara dà á nígbà tóun náà ní ìdààmú ọkàn. A tún máa kẹ́kọ̀ọ́ lára àwọn míì tó yíjú sí Jèhófà nígbà tí wọ́n ní ìdààmú ọkàn.