ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

a Tá a bá ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn tó fòótọ́ ọkàn sin Jèhófà, àpẹẹrẹ gidi ni Lọ́ọ̀tì, Jóòbù àti Náómì jẹ́, síbẹ̀ wọ́n kojú àwọn ìṣòro tó le gan-an. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò ohun tá a lè kọ́ látinú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí wọn. A tún máa jíròrò ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká máa mú sùúrù fáwọn ará wa tó ń kojú ìṣòro, ká máa fi àánú hàn sí wọn, ká sì máa sọ̀rọ̀ ìtùnú fún wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́