Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀWÒRÁN: Ọkùnrin kan tó ń rìnrìn àjò gba ìwé kan lọ́dọ̀ àwọn Ẹlẹ́rìí tó pàtẹ ìwé ní ibùdókọ̀ òfúrufú. Nígbà tó dé ibi tó ń lọ, ó tún rí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà níbi tí wọ́n pàtẹ ìwé sí. Nígbà tó délé, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà wá wàásù fún un.