Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Kí ló yẹ ká ṣe tí ìjọba bá ṣòfin pé ká má ṣe jọ́sìn Jèhófà mọ́? Àpilẹ̀kọ yìí máa sọ àwọn ohun pàtó tá a lè ṣe àtàwọn ohun tó yẹ ká yẹra fún ká lè máa sin Jèhófà nìṣó.