Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d ÀWÒRÁN: Àwọn ọlọ́pàá ń wádìí ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu arákùnrin kan, àmọ́ ó kọ̀ láti sọ ohunkóhun fún wọn nípa àwọn ará.