Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Inú wa máa dùn táwọn mọ̀lẹ́bí wa bá yàn láti sin Jèhófà, àmọ́ àwọn ló máa pinnu bóyá wọ́n á ṣe bẹ́ẹ̀ àbí wọn ò ní ṣe bẹ́ẹ̀. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa rí àwọn ohun tá a lè ṣe táá mú kó wù wọ́n láti fetí sí wa.