Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
e ÀWÒRÁN: Arábìnrin náà pe àwọn ará ìjọ rẹ̀ wá sílé wọn. Àwọn ará yẹn ṣe gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe láti túbọ̀ sún mọ́ ọkọ arábìnrin náà. Nígbà tó yá, ọkùnrin náà tẹ̀ lé ìyàwó ẹ̀ lọ sí Ìrántí Ikú Kristi.