Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àsìkò tá a wà yìí gan-an ló yẹ ká túbọ̀ fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ àwọn ará wa. Lẹ́tà tí Pọ́ọ̀lù kọ sáwọn ará Fílípì máa jẹ́ ká rí bá a ṣe lè túbọ̀ fìfẹ́ hàn sáwọn ará, kódà nígbà tó bá ṣòro láti ṣe bẹ́ẹ̀.