Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Bákan náà, táwọn arákùnrin tó ní ojúṣe pàtàkì nínú ètò Ọlọ́run bá ti dé ọjọ́ orí kan, wọ́n máa ń fi ojúṣe náà sílẹ̀ fáwọn arákùnrin tí kò tó wọn lọ́jọ́ orí. Wo àpilẹ̀kọ náà, “Ẹ̀yin Àgbàlagbà—Jèhófà Mọyì Iṣẹ́ Yín” nínú Ilé Ìṣọ́ September 2018, àti “Bó O Ṣe Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn Láìka Ìyípadà Èyíkéyìí Sí” nínú Ilé Ìṣọ́ October 2018.