Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀ wà lára àwọn ànímọ́ tó ṣe pàtàkì jù tó yẹ ká ní. Kí ló túmọ̀ sí pé kéèyàn lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀? Kí nìdí tó fi yẹ ká lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀? Kí sì nìdí tó fi máa ń ṣòro láti lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀ tí ipò nǹkan bá yí pa dà fún wa? A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ yìí.