Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa rí ìdí tó fi yẹ ká fi ara wa sábẹ́ Jèhófà. A tún máa jíròrò ohun táwọn tó ní ọlá àṣẹ ìyẹn àwọn alàgbà, àwọn bàbá àtàwọn ìyá máa rí kọ́ lára Gómìnà Nehemáyà, Ọba Dáfídì àti Màríà ìyá Jésù.