Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀLÀYÉ Ọ̀RỌ̀: Ojú ẹni tó ń sìnrú lọ̀pọ̀ máa fi ń wo ẹni tó fi ara rẹ̀ sábẹ́ àwọn míì. Àmọ́, tọkàntọkàn làwa èèyàn Jèhófà fi ń ṣègbọràn sí i, torí náà a kì í wò ó bíi pé ṣe ló ń fipá mú wa ṣègbọràn.