Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a A mọ̀ pé láìpẹ́ “ìpọ́njú ńlá” máa dé bá gbogbo aráyé. Torí náà, kí ló máa ṣẹlẹ̀ sáwa ìránṣẹ́ Jèhófà lásìkò yẹn? Kí ni Jèhófà máa fẹ́ ká ṣe nígbà yẹn? Àwọn ànímọ́ wo ló yẹ ká ní báyìí ká lè jẹ́ olóòótọ́ nígbà ìpọ́njú ńlá? A máa rí ìdáhùn nínú àpilẹ̀kọ yìí.