Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìjíròrò nípa àwọn nǹkan tó máa ṣẹlẹ̀ títí wọ ogun Amágẹ́dọ́nì, wo orí 21 nínú ìwé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso! Tó o bá fẹ́ àlàyé sí i nípa ìgbéjàko Gọ́ọ̀gù ti ilẹ̀ Mágọ́gù àti bí Jèhófà ṣe máa gbèjà àwọn èèyàn rẹ̀ nígbà ogun Amágẹ́dọ́nì, wo orí 17 àti 18 nínú ìwé Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!