Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé h ÀWÒRÁN: Ogunlọ́gọ̀ èèyàn tó jẹ́ ìránṣẹ́ Jèhófà máa la ìpọ́njú ńlá náà já, wọ́n á wà láàyè, wọ́n á sì máa láyọ̀!