Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ṣé ó máa ń ṣe ẹ́ bíi pé o ò ṣe tó lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà? Ṣé o máa ń ronú pé bóyá lo ṣì wúlò fún Jèhófà? Àbí o máa ń ronú pé èyí tó ò ń ṣe báyìí ti tó? Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò bí Jèhófà ṣe lè mú kó máa wù ẹ́ láti di ohunkóhun kó o lè mú ìfẹ́ rẹ̀ ṣẹ àti bó ṣe máa fún ẹ lágbára láti ṣe é.