Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bí òpin ṣe ń sún mọ́lé, ó ṣe pàtàkì pé kí gbogbo wa túbọ̀ ṣera wa lọ́kan. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò ohun tá a rí kọ́ lára Jeremáyà. A tún máa sọ̀rọ̀ nípa àǹfààní tá a máa rí tá a bá ṣera wa lọ́kan nísinsìnyí kí ìṣòro tó dé àti bí ìyẹn ṣe máa ràn wá lọ́wọ́ nígbà àdánwò.