Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c ÀWÒRÁN: Àwòrán yìí jẹ́ ká rí ohun tó ṣeé ṣe kó ṣẹlẹ̀ nígbà “ìpọ́njú ńlá.” Àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin kan forí pa mọ́ sínú iyàrá arákùnrin kan. Gbogbo wọn ń tura wọn nínú lásìkò tí nǹkan le gan-an. Àwọn àwòrán mẹ́ta tó tẹ̀ le é yìí fi hàn pé àwọn ará yẹn ti di ọ̀rẹ́ ara wọn kí ìpọ́njú ńlá tó bẹ̀rẹ̀