Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Nínú gbogbo àwọn tó kọ ìwé Ìhìn Rere, Lúùkù ló jẹ́ ká mọ̀ pé Jésù ò fọ̀rọ̀ àdúrà ṣeré.—Lúùkù 3:21; 5:16; 6:12; 9:18, 28, 29; 18:1; 22:41, 44.