Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ṣé o máa ń kábàámọ̀ àwọn ìpinnu tó o ṣe nígbà míì? Àbí ó máa ń ṣòro fún ẹ láti ṣèpinnu tó mọ́gbọ́n dání kó o sì gbé ìgbésẹ̀ lórí ẹ̀? Nínú àpilẹ̀kọ yìí, wàá rí ohun tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí ìṣòro yẹn kó o lè parí ohun tó o bẹ̀rẹ̀.