Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àwọn òfin tí Jèhófà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àtijọ́ ló wà nínú ìwé Léfítíkù. Òótọ́ ni pé àwa Kristẹni kò sí lábẹ́ àwọn òfin yẹn, síbẹ̀ wọ́n lè ṣe wá láǹfààní. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì kan tá a lè rí kọ́ nínú ìwé Léfítíkù.