Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ohun ọlọ́wọ̀ ni tùràrí tí wọ́n máa ń sun nínú àgọ́ ìjọsìn, inú ìjọsìn Jèhófà nìkan ni wọ́n sì ti máa ń lò ó ní Ísírẹ́lì àtijọ́. (Ẹ́kís. 30:34-38) Kò sí ẹ̀rí kankan tó fi hàn pé àwọn Kristẹni ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní sun tùràrí nígbà tí wọ́n ń jọ́sìn Jèhófà.