Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d ÀWÒRÁN: Àlùfáà àgbà wọnú Ibi Mímọ́ Jù Lọ ní Ọjọ́ Ètùtù, ó fi ọwọ́ kan gbé tùràrí dání, ó sì fi ọwọ́ kejì gbé ìkóná tó kún fún ẹyin iná. Lẹ́yìn tó da tùràrí sínú ẹyin iná, gbogbo iyàrá náà kún fún òórùn dídùn. Ẹ̀yìn ìyẹn ló tún pa dà wá sínú Ibi Mímọ́ Jù Lọ láti fi ẹ̀jẹ̀ rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.