Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
h ÀWÒRÁN: Ní February 2019, Arákùnrin Gerrit Lösch tó jẹ́ ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí mú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe jáde lédè German, inú àwọn èèyàn tó pé jọ sì dùn gan-an. Lónìí, bíi tàwọn arábìnrin méjì yìí, àwọn akéde Ìjọba Ọlọ́run tó wà lórílẹ̀-èdè Jámánì ń fayọ̀ lo Bíbélì tuntun yìí lóde ẹ̀rí.