Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé Mímọ́ jẹ́ ká mọ irú ọwọ́ tó yẹ ká fi mú iṣẹ́ àti ìsinmi. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa lo àpẹẹrẹ Sábáàtì táwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń pa mọ́ lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ láti ṣàlàyé bá a ṣe lè máa fojú tó tọ́ wo iṣẹ́ àti ìsinmi.