Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọ̀pọ̀ èèyàn ló gbà pé Ọlọ́run wà, àmọ́ wọn ò mọ̀ ọ́n dunjú. Kí ló túmọ̀ sí tá a bá sọ pé ẹnì kan mọ Jèhófà? Kí la lè rí kọ́ nínú bí Mósè àti Ọba Dáfídì ṣe mọ Jèhófà dunjú tí wọ́n sì tún jẹ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀? A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ yìí.