Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a b Àkíyèsí: Bẹ̀rẹ̀ láti oṣù yìí, yàtọ̀ sí ìtọ́ni tí akẹ́kọ̀ọ́ kọ̀ọ̀kan máa tẹ̀ lé, a tún máa kọ kókó tó máa ṣiṣẹ́ lé lórí nínú ìwé pẹlẹbẹ Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni (th) sínú àkámọ́.